Ìròyìn nípa Ìròyìn Ọmọ-ìlú láti Ọ̀wẹwẹ̀ , 2019
Ìtọ́jú àwọn erin aláìlóbìíi Myanmar
Erin ẹgàn-an Myanmar ń bẹ ń'nú ewu, àwọn adẹ́mìí légbodò kò jẹ́ kí wọn ó gbáyé, erin kan lọ́sẹ̀ kan ni wọ́n ń pa.
O rí gbogbo èdè òkè wọ̀nyẹn? A ṣe ìtumọ̀ ìròyìn Global Voices (Ohun Àgbáyé) láti mú ìròyìn ará ìlú àgbáyé sétígbọ̀ọ́ ènìyàn gbogbo.
Erin ẹgàn-an Myanmar ń bẹ ń'nú ewu, àwọn adẹ́mìí légbodò kò jẹ́ kí wọn ó gbáyé, erin kan lọ́sẹ̀ kan ni wọ́n ń pa.