Ìròyìn nípa Ọ̀dọ́
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sààmì Àjọ̀dún ọdun 64 tí ó gba òmìnira nínú òjòjò ètò ọ̀rọ̀ Ajé àti ìfẹ̀hónúhàn
"Òmìnira àbí omi ìnira. Àwọn òyìnbó amúnisìn gan-an sàn ju àwaarawa tí à ń darí orílẹ̀-èdè yìí lọ. Àwọn ọ̀jẹ̀lú ló ń tukọ̀ ìjọba wa kì í ṣe òṣèlú..."
Ìlàkàkà láti fi òpin sí òkúrorò SARS ẹ̀ka ilé-isẹ́ ọlọ́pàá ilẹ̀ Nàìjííríà ń tẹ̀síwájú.
Ìbéèrè lórí ẹni tí ó ń darí àwọn Ọlọ́pàá àti ikọ̀ SARS kò tíì fi gbogbo ara rí ìdáhùn. Ìwé-òfin ilẹ̀ náà gbágbára ìdárí lé ààrẹ lọ́wọ́, ó sì gbé agbára àmójútó lé Ọ̀gá àgbà ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá lọ́wọ́.
Àwọn ìdílé l’órílẹ̀-èdè Kenya fi ara kááṣá látàrí ipa ìfọjọ́-kún ilé-ìwé tí ó wà ní títì pa
Látàrí títì pa àwọn ilé-ìwé ní orílẹ̀-èdè Kenya, àìdọgba ti kọjá bẹ́ẹ̀. Àwọn amòye nídìí ètò-ẹ̀kọ́ fẹ́ kí ìjọba tún iná ètò-ẹ̀kọ́ dá látì lè jẹ́ kí ìkẹ́kọ̀ọ́ ó kárí tẹrútọmọ
Ilé ẹjọ́ gíga Tanzania pa á láṣẹ fún ìfòpinsí ìsoyìgì láàárín àgbàlagbà àti ọmọdé láì wo ti ìgbésẹ̀ ìmúpadàa rẹ̀
Nínú oṣù Ọ̀wàrà 2019, Ilé-ẹjọ́ Gíga Tanzania ṣe ìdímú ṣinṣin ìdájọ́ láti fòpin sí ìgbéyàwó ọmọdé. Ìdájọ́ ilé ẹjọ́ náà jẹ́ atọ́ka sí ìfòpinsí àwọn àṣà tí ó ń mú ìpalára bá àwọn ọmọdébìnrin àti onírúurú ẹlẹ́yàmẹyà tòun ìfọwọ́rọ́sẹ́yìn àwọn ọmọdébìnrin.
#SexForGrades: Ètò Alálàyé-afẹ̀ríhàn tú àṣìírí ìwà ìyọlẹ́nu ìbálòpọ̀ ní àwọn Ifásitìi Ìwọ-oòrùn Ilẹ̀-Adúláwọ̀
Professors who harass female students and pressure them for sex in return for grades or school admission has become the norm in many universities in Nigeria and Ghana.
Ilé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ orin kíkọ kan ṣoṣo ní Zanzibar ti fẹ́ di títì pa
For the 1,800 talented students who have trained at the DCMA, this is the only musical home they know, where they can learn and grow as professional musicians and artists.
Àyájọ́ Ọjọ́ Òmìnira ní Trinidad àti Tobago — àmọ́ ǹjẹ́ orílẹ̀-èdè náà ní òmìnira bí?
"Òmìnira yìí faramọ́ ẹni tí o jẹ́, ibi tí o ti ṣẹ̀ wá, ẹ̀jẹ̀ àti ìṣẹ̀lẹ̀-àtẹ̀yìwá tí ó wà nínú iṣan-ẹ̀jẹ̀ rẹ"
‘Ohùn-un Jamaica fún Àyípadà Ojú-ọjọ́’ fi orin jíṣẹ́ẹ wọn
Iléeṣẹ́ tí kì í ṣe ti ìjọba ń ṣe ìgbélárugẹ àwọn ọ̀nà tí a lè gba jẹ́ iṣẹ́ yìí nípa lílo iṣẹ́ ọpọlọ orin láti kéde nípa àyípadà ojú-ọjọ́.
Burundi: Kọ Ìkọkúkọ sórí àwòrán Ààrẹ — kí o wẹ̀wọ̀n
"Bí mo bá ṣe èyí ní Burundi ti Nkurunziza, Mo lè wẹ̀wọ̀n."
‘Ẹ Yé é Pa Àwọn Òbìnrin’ – ìpolongo tuntun tí ó ń tako ìjìyà inú ìgbéyàwó ní Angola
"Violence against women is real, it really is. It is not something in the heads of feminists, it is not an invention or empty speech: IT IS REAL!"