· Òkúdù , 2019

Ìròyìn nípa Ìròyìn Ọmọ-ìlú láti Òkúdù , 2019

Ojúṣe láti ṣe ìrántí: ọgbọ̀n ọdún lẹ́yìn Tiananmen

4 Òkúdù 2019

Ní 1989, ikọ̀ ogun orílẹ̀-èdè China ṣíná bolẹ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó ń ṣe ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn àtúnṣe ètò ìjọba àwarawa tí ó fa ìpaninípakúpa nínúu Gbàgede Tiananmen Square ní ọjọ́ 4 oṣù Òkúdù. Fún 30 ọdún, a ṣe ìrántí ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyẹn àti arapa wọn.