Ìròyìn nípa Ìròyìn Ọmọ-ìlú láti Ọ̀pẹ, 2019
Ìwé àbádòfin ìlò ẹ̀rọ alátagbà yóò pa òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ lórí ayélujára ní Nàìjíríà
Ìwé àbádòfin ìlò ẹ̀rọ alátagbà náà yóò pa òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ lórí ayélujára, sọ ìtakò ìjọba d'ẹ̀ṣẹ̀ àti sọ ìṣánpa ẹ̀rọ ayélujára ní Nàìjíríà dòfin.