Ìròyìn asọ̀tàn nípa Ẹ̀tọ́ Ìbálòpọ̀-akọakọ-aboabo (LGBT)
Ìròyìn nípa Ẹ̀tọ́ Ìbálòpọ̀-akọakọ-aboabo (LGBT)
Ilé-iṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Ìbílẹ̀ Fagilé Ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú àwọn ajìjàǹgbara LGBT lẹ́yìn ìhalẹ̀mọ́ sí olóòtú
Èébú ìkórìíra-ìbálòpọ̀-láàárín-akọ-àti-akọ ní orí ayélujára kò ṣí ọkàn-an olóòtú kúrò, àmọ́ ìpè ẹni àjèjì ń dá ẹ̀ru ìwà ìkà bá àwọn àlejòo rẹ̀.
Ìwọ́de afẹ́ àwọn abódiakọ-akọ́diabo àkọ́kọ́ lè tú èrò nípa wọn ní Pakístánì ká
The first transgender pride march seeks to change stereotypes and demand rights.