Àkànṣe Ìròyìn

Lórí ojúewé wọ̀nyí ni a ti máa ń ṣe ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àkótán àwọn ìròyìn Ohùn Àgbáyé (Global Voices) tó jẹ́ gbòògì tí a mú láti àwọn búlọ̀ọ̀gù àti ìròyìn ọmọ-ìlú kárí àgbáyé. Bí o bá ní àbá ojúewé àkànṣe ìròyìn tuntun, jọ̀wọ́ fi ímeèlì ṣọwọ́ sí wa.