Ìròyìn nípa Ìròyìn Ọmọ-ìlú láti Agẹmọ , 2019
Àwọn ọmọ Bangladeshi lo ẹ̀rọ-alátagbà fi gbógun ti àjàkálẹ̀ àìsàn ibà-ẹ̀fọn
Pẹ̀lú ìkéde àti ètò tí kò tó nǹkan láti ọ̀dọ̀ ìjọba, àwọn ènìyàn ti ń kọrí sí ẹ̀rọ-alátagbà lọ láti k’ẹ́kọ̀ọ́ àti kéde nípa ibà-ẹ̀fọn