Ìròyìn asọ̀tàn nípa Ìṣípò àti Ìṣílọ-sí-ìlù-mìíràn
Ìròyìn nípa Ìṣípò àti Ìṣílọ-sí-ìlù-mìíràn
Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà fi òfin de ìrìn-àjò lójúnà ìṣàmójútó àwọn tó ti kó kòkòrò àìfojúrí COVID 19
Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lórí ayélujára béèrè fún ìfòfindè arìnrìnàjò láti orílẹ̀-èdè tí COVID-19 ti gbilẹ̀. Èyí á ró ojúṣẹ́ orílẹ̀-èdè sí ìtànkálẹ̀ yìí lágbára.
Ìrìn-àjò: Ìpẹ̀kun eré-ìdárayá fún Ọmọ-adúláwọ̀
Ó ṣòro fún Ọmọ-adúláwọ̀ láti ṣèrìnàjò jáde kúrò ní Ilẹ̀-adúláwọ̀ — ṣùgbọ́n bẹ́ẹ̀ náà ni ó nira láti rìrìnàjò láàárín ilẹ̀ náà.
Ìjọba Tanzania fi Ajìjàgbara Ọmọ Orílẹ̀-èdèe Uganda sí àtìmọ́lé, wọ́n sì lé e kúrò nílùú
Human Rights Watch sọ wípé Orílẹ̀ èdèe Tanzania ti rí "ìrésílẹ̀ ìbọ̀wọ̀ fún òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ, ìkẹ́gbẹ́ àti àpéjọ dé ojú àmì" lábẹ́ ìṣàkóso ìjọba tí ó ń tukọ̀.