Ìròyìn asọ̀tàn nípa Middle East & North Africa
Ìròyìn nípa Middle East & North Africa
Boji rè é, Ajá tí ó máa ń jayé orí i rẹ̀ kiri ìgboro Istanbul nínú ọkọ̀ èrò
Ẹ pàdé Boji, Ajá kan ni Istanbul tí ó máa ń wọ ọkọ̀ èrò kiri ìgboro lójoojúmọ́.
Ní àwọn ìlú tí ó wà lábẹ́ ìṣàkóso Assad ní ilẹ̀ Syria, àwọn alákòóso sọ báyìí pé ‘kò sí èni tí ó ní àrùn kòrónà’
Láti tẹnpẹlẹ mọ́ ìṣàkóso, sáà Assad ṣe ohun gbogbo tí ó lè ṣe ní ti ìkọ̀jálẹ̀ wí pé kò sí COVID-19 ní àwọn agbègbè tí ó wà lábẹ̀ ìṣàkóso rẹ̀.
100 ọjọ́ fún Alaa: Ẹbí ajàfúnẹ̀tọ́ ọmọ Íjípìtì ń ka ọjọ́ fún ìdásílẹ̀ẹ rẹ̀ nínú ẹ̀wọ̀n
Alaa has been jailed or investigated under every Egyptian head of state who has served during his lifetime.