Ìròyìn nípa Ìròyìn Ọmọ-ìlú láti Èrèlé , 2023
Ọ̀rọ̀ Ààbò Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá…ní èdè wa. Àwọn Àbá láti ọwọ́ onígbèjà èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
"Àǹfààní fún àwọn elédè Yorùbá ò tó nítorí kò sí àwọn ohun àmúlò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá wọ̀nyí ní èdè abínibí wọn, èyí tí ó dákun àìsí àṣà ààbò orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá tó péye láàárín àwùjọ náà."