Babátúndé Pópóọlá

BABATÚNDÉ ỌLÁṢAYỌ̀ PÓPÓỌLÁ holds a Bachelor of Degree in view in Linguistics/Yoruba from University of Lagos. His final year thesis is on “The used of Oral Literature in Afọ̀njá movie” Supervisor: Caleb S. Ọ̀wọ́adé M.A. (LAGOS)

He is currently a Research Assistant to Prof. Ọlàdiípọ̀ Ajíbóyè of the Department of Linguistics African and Asian Studies, Unilag and Dr. Abísóyè Ẹlẹ́shin of Institute of African and Diaspora Studies, (I.A.D.S.) University of Lagos in a project titled “Yorùbá Indigenous Advertisement”

He is also a Translator, Newscaster and a Radio Presenter in UNILAG103.1FM.

He has received numerous academics awards. He is a Yorùbá Teacher, a Poet and an advocate of Yorùbá culture..

Ímeèlì Babátúndé Pópóọlá

Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Babátúndé Pópóọlá

Rising Voices’ Activismo Lenguas gba Àmì-ẹ̀yẹ Èdè Abínibí Àgbáyé

"Àmì-ẹ̀yẹ yìí dúró gẹ́gẹ́ bí ipa tí àwọn ajìjàngbara èdè lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ń ní jákèjádò agbègbè Latin Amẹ́ríkà àti arapa ribiribi iṣẹ́ wọn."

Ìlàkàkà láti fi òpin sí òkúrorò SARS ẹ̀ka ilé-isẹ́ ọlọ́pàá ilẹ̀ Nàìjííríà ń tẹ̀síwájú.

Ìbéèrè lórí ẹni tí ó ń darí àwọn Ọlọ́pàá àti ikọ̀ SARS kò tíì fi gbogbo ara rí ìdáhùn. Ìwé-òfin ilẹ̀ náà gbágbára ìdárí lé...

‘Boca de Rua': Ìwé ìròyìn ilẹ̀ brazil láti ọwọ́ àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ní ojú òpópónà

Wọ́n dá a sílẹ̀ ní nǹkan bi 20 ọdún sẹ́yìn. ‘Boca de Rua’ nìkan ni ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Àwọn Ìwé Ìròyìn Ẹsẹ̀kùkú Àgbáyé tí...

Àwọn ìdílé l’órílẹ̀-èdè Kenya fi ara kááṣá látàrí ipa ìfọjọ́-kún ilé-ìwé tí ó wà ní títì pa

Látàrí títì pa àwọn ilé-ìwé ní orílẹ̀-èdè Kenya, àìdọgba ti kọjá bẹ́ẹ̀. Àwọn amòye nídìí ètò-ẹ̀kọ́ fẹ́ kí ìjọba tún iná ètò-ẹ̀kọ́ dá látì lè...