Ìròyìn asọ̀tàn nípa Latin America
Ìròyìn nípa Latin America
Fún ìgbà àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdèe Brazil, ọmọ ìbílẹ̀ lóbìnrin di ọmọ ìgbìmọ̀ ìjọba
Joenia ni ọmọ ìbílẹ̀ lóbìnrin àkọ́kọ́ tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin ní Brazil, òun sì ni agbẹjọ́rò tí ó jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò gbejọ́rò ní Ilé-ẹjọ́ Gíga jùlọ.
Oníròyìn Orí ẹ̀rọ-alátagbà Luis Carlos Diaz di àwátì ní Venezuela
Luis Carlos "jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó síwájú nínú akọ̀ròyìn tako ìgbésẹ̀ ìjọba ní Venezuela".