Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Ọmọ Yoòbá láti Ẹrẹ́nà , 2019
Oníròyìn Orí ẹ̀rọ-alátagbà Luis Carlos Diaz di àwátì ní Venezuela

Luis Carlos "jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó síwájú nínú akọ̀ròyìn tako ìgbésẹ̀ ìjọba ní Venezuela".
Àfilé iye owó fún gbígba ìwé ẹ̀rí ọmọ-ìlú-fún-ìrìnnà mú àwọn ọmọ Angola fi ẹ̀hónú hàn
Iye owó ìwé ẹ̀rí náà fò sókè láti owó dollar orílẹ̀-èdè US 8 sí 97.