Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Ọmọ Yoòbá láti Ọ̀wẹwẹ̀ , 2019
Ìtọ́jú àwọn erin aláìlóbìíi Myanmar
Erin ẹgàn-an Myanmar ń bẹ ń'nú ewu, àwọn adẹ́mìí légbodò kò jẹ́ kí wọn ó gbáyé, erin kan lọ́sẹ̀ kan ni wọ́n ń pa.