Ìròyìn nípa Ìlú Gúúsù Aṣálẹ̀ Sahara láti Ògún , 2019
Ìrìn-àjò: Ìpẹ̀kun eré-ìdárayá fún Ọmọ-adúláwọ̀
Ó ṣòro fún Ọmọ-adúláwọ̀ láti ṣèrìnàjò jáde kúrò ní Ilẹ̀-adúláwọ̀ — ṣùgbọ́n bẹ́ẹ̀ náà ni ó nira láti rìrìnàjò láàárín ilẹ̀ náà.