Ìròyìn nípa Ìlú Gúúsù Aṣálẹ̀ Sahara láti Ògún , 2020
Àwọn ìdílé l’órílẹ̀-èdè Kenya fi ara kááṣá látàrí ipa ìfọjọ́-kún ilé-ìwé tí ó wà ní títì pa
Látàrí títì pa àwọn ilé-ìwé ní orílẹ̀-èdè Kenya, àìdọgba ti kọjá bẹ́ẹ̀. Àwọn amòye nídìí ètò-ẹ̀kọ́ fẹ́ kí ìjọba tún iná ètò-ẹ̀kọ́ dá látì lè jẹ́ kí ìkẹ́kọ̀ọ́ ó kárí tẹrútọmọ