Ìròyìn nípa Ìlú Gúúsù Aṣálẹ̀ Sahara láti Ọ̀pẹ, 2018
Kí ló dé tí ìjọba Ilẹ̀-Adúláwọ̀ ń f'òfin de ọ̀rọ̀ sísọ orí-ayélujára? Nítorí wọ́n bẹ̀rù agbára rẹ̀.
The noise we make on digital platforms scares oppressive regimes. In some cases, it can even force them to rescind their actions.
Òṣìṣẹ́ inú ọkọ̀ òfuurufú olóbìrin nìkan wọ ìwé ìtàn ní Mozambique
For the first time in the country's civil aviation history, an airplane was operated entirely by women.