Ìròyìn nípa Ìlú Gúúsù Aṣálẹ̀ Sahara láti Ṣẹẹrẹ, 2019
Mọ àwọn òǹdíje sí ipò ààrẹ Nàìjíríà ọdún 2019
Ìdíje fún Àpáta Agbára ti ń lọ — àga Ààrẹ orílẹ̀-èdèe Nàìjíríà. Mọ àwọn òǹdíje sí ipò ààrẹ Nàìjíríà ọdún-un 2019.
‘Ẹ Yé é Pa Àwọn Òbìnrin’ – ìpolongo tuntun tí ó ń tako ìjìyà inú ìgbéyàwó ní Angola
"Violence against women is real, it really is. It is not something in the heads of feminists, it is not an invention or empty speech: IT IS REAL!"
Ìjàm̀bá Àwọn Ológun Mauritania 28 tí wọ́n pa ní ọjọ́ Òmìnira tí a kò sọ
"Great nations ... never try to erase a dark episode out of their history, but instead, show it to the world for everyone to remember and say 'NEVER AGAIN'."