Ìròyìn nípa Ẹ̀tọ́ Ìbálòpọ̀-akọakọ-aboabo (LGBT) láti Ṣẹẹrẹ, 2023
Wọ́n pẹ̀gàn àwọn ọkùnrin aperawọnlóbìnrin, gẹ́gẹ́ bí i Wúńdíá Màríà lójú ayé rẹ̀
"Mo jẹ́ ìyá tí ó ń tọ́ ọmọ rẹ̀. Kò sí pé ọlẹ̀ sọ nínú mi, ṣùgbọ́n fún èmi, ìyanu ni ó jẹ́."
Àjọ tí ó ń rí sí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ní Turkey ní àwọn obìnrin ò le dá nìkan rin ìrìn-àjò
Ìgbà àkọ́kọ́ tí àjọ ẹ̀sìn ní ìlú Turkey yóò lépa àwọn obìnrin àti òmìnira wọn kọ́ lèyìí, tí ó sì tún ń yẹpẹrẹ wọ́n láwùjọ.