· Ọ̀wẹwẹ̀ , 2019

Ìròyìn nípa Myanmar (Burma) láti Ọ̀wẹwẹ̀ , 2019

Ìtọ́jú àwọn erin aláìlóbìíi Myanmar

Erin ẹgàn-an Myanmar ń bẹ ń'nú ewu, àwọn adẹ́mìí légbodò kò jẹ́ kí wọn ó gbáyé, erin kan lọ́sẹ̀ kan ni wọ́n ń pa.