Ìròyìn nípa Central Asia & Caucasus
Olórí orílẹ̀-èdè Azerbaijan tàkùrọ̀sọ àkọ́kọ́ ní orí amóhùnmáwòrán lẹ́yìn ọdún 15 ní orí àlééfà. Ó lè lo ọ̀nà mìíràn.
"Ọ̀rọ̀ ìparíì mi: ara ò rọ ìjọba rárá!"
O rí gbogbo èdè òkè wọ̀nyẹn? A ṣe ìtumọ̀ ìròyìn Global Voices (Ohun Àgbáyé) láti mú ìròyìn ará ìlú àgbáyé sétígbọ̀ọ́ ènìyàn gbogbo.
"Ọ̀rọ̀ ìparíì mi: ara ò rọ ìjọba rárá!"