Ìròyìn nípa Òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ láti Ògún , 2020
Ní orílẹ̀-èdè Turkey, ẹgbẹẹgbẹ̀rún méjì àbọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ni wọ́n jókòó ṣe ìdánwò ìgbaniwọlẹ́ sí Ifásitì
Awuyewuye wà lórí ìdáwò ọdún yìí -- kò sì kín ṣe látàri àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19.