Ìròyìn nípa Òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ láti Èrèlé , 2019
Pẹ̀lú àìbalẹ̀-ọkàn tí ó ń pọ̀ sí i ní ìmúra ìbò ààrẹ ọdún-un 2019, Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń bẹ̀rùu pípa ẹ̀rọ-ayélujára
Lílo ẹ̀rọ-alátagbà fún pípe àkíyèsí sí ìrúfin ìjọba àti ìwà tí kò bá òfin mu ti fa ìbẹ̀rù wípé ìtẹríbọlẹ̀ ní orí ayélujára ní àsìkò ìbò tí ó ń bọ̀.