Ìròyìn nípa Òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ láti Ṣẹẹrẹ, 2023
A lé òǹṣàmúlò TikTok Nekoglai láti Moscow padà sí Moldova pẹ̀lú àmì lúlù
“Orò ìjẹ̀bi àti ìtìjú” náà ni àwọn agbófinró orílẹ̀-èdè Russia pọwọ́lé lílò rẹ̀ láti fi “àbámọ̀” náà hàn ní gbangba àti ìpayà àwọn afẹ̀hónúhàn