Ìwò-ojú Afárá (Bridge) náà ní àròkọ, ìṣàlàyé, àti ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ tí ó tan ìmọ́lẹ̀ sí ìyàtọ̀ ìfojúwò láàárín ìṣọwọ́kọ̀ròyìn ìbílẹ̀ àti ti òkèèrè, láti ọ̀nà mìíràn gedegbe tí àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ẹ Global Voices fi kọ tiwọn. Kì í ṣe wípé ọ̀nà tí a gbà kọ ìròyìn jẹ́ ìpínnu gbogboògbò.

RSS

Ìròyìn nípa Afárá Náà láti Èrèlé , 2019

Jẹ́ kí àwọn òkú ó sọ ìtàn nípa Hong Kong

"Ìrìnàjò afẹ́ ìpànìyàn" tí ó ń lépa láti ṣe àyẹ̀wò fínnífínní sí" ìtúmọ̀ ayé àti ìgbé-àyè" ní àyìkà agbègbè orílẹ̀-èdèe Hong Kong.