Ìròyìn nípa Afárá Náà láti Ṣẹẹrẹ, 2023
Wọ́n pẹ̀gàn àwọn ọkùnrin aperawọnlóbìnrin, gẹ́gẹ́ bí i Wúńdíá Màríà lójú ayé rẹ̀
"Mo jẹ́ ìyá tí ó ń tọ́ ọmọ rẹ̀. Kò sí pé ọlẹ̀ sọ nínú mi, ṣùgbọ́n fún èmi, ìyanu ni ó jẹ́."
Ó rọrùn, lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, ó sì bani nínú jẹ́ — òṣùwọ̀n àwọn àjọ̀dún
" ... Ohun tí mo ní pẹ̀lú Ọjọ́ Àìsùn Ọdún tuntun wá láti èrò ìgbà èwe, èrò tó fi yé mi pé àwọn idán àràmàndà lè ṣẹlẹ̀."