Bẹlu , 2021

Ìròyìn láti Bẹlu , 2021

Boji rè é, Ajá tí ó máa ń jayé orí i rẹ̀ kiri ìgboro Istanbul nínú ọkọ̀ èrò

Ẹ pàdé Boji, Ajá kan ni Istanbul tí ó máa ń wọ ọkọ̀ èrò kiri ìgboro lójoojúmọ́.