Agẹmọ , 2022

Ìròyìn láti Agẹmọ , 2022

Súyà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà!

Mọ́là kan ni a rí níbí tí ó jókòó sídìí Àtẹ Súyà rẹ̀ Súyà (tí wọ́n ń pè é báyìí pé Sú-yá-à) Ìyẹn ni orúkọ ìjànjá-ẹran kan tí a ń yan lórí ayanran tó fẹjú, pẹ̀lú òróró, àlùbọ́sà àti iyọ̀. Súyà jẹ́ gbajúgbajà ohun jíjẹ láàárín àwọn ọlọ́rọ̀ àti bọ̀rọ̀kìní...