Ìròyìn nípa Ẹ̀yà àti ìran láti Èrèlé , 2019
Akẹ́kọ̀ọ́bìrin kan tí ó jẹ́ ọmọ Tibet-Canada rí ìkọlu lórí ayélujára lẹ́yìn tí ó já ewé olú borí nínú ìdìbò àjọ-ìgbìmọ̀ akẹ́kọ̀ọ́. Ó rò pé, Beijing ló yẹ á bá wí.
Chemi Lhamo dojú kọ onírúurú èsì ìdáyàjáni ní orí ẹ̀rọ-alátagbà láti ẹnu àwọn akẹ́kọ̀ọ́ òkè-òkun tí ó ń gbé ní gbùngbùn orílẹ̀-èdè China.