Ìròyìn nípa Ìjàfúnẹ̀tọ́ Ẹ̀rọ-ìgbàlódé láti Ṣẹẹrẹ, 2019
‘Ẹ Yé é Pa Àwọn Òbìnrin’ – ìpolongo tuntun tí ó ń tako ìjìyà inú ìgbéyàwó ní Angola
"Violence against women is real, it really is. It is not something in the heads of feminists, it is not an invention or empty speech: IT IS REAL!"
100 ọjọ́ fún Alaa: Ẹbí ajàfúnẹ̀tọ́ ọmọ Íjípìtì ń ka ọjọ́ fún ìdásílẹ̀ẹ rẹ̀ nínú ẹ̀wọ̀n
Alaa has been jailed or investigated under every Egyptian head of state who has served during his lifetime.