A researcher, language lover and YorEng translator. I am passionate about language documentation, teaching and research.
Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Ọmọ́dásọ́lá
Àjọ tí ó ń rí sí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ní Turkey ní àwọn obìnrin ò le dá nìkan rin ìrìn-àjò
Ìgbà àkọ́kọ́ tí àjọ ẹ̀sìn ní ìlú Turkey yóò lépa àwọn obìnrin àti òmìnira wọn kọ́ lèyìí, tí ó sì tún ń yẹpẹrẹ wọ́n láwùjọ.