Ìròyìn nípa Ìlú Gúúsù Aṣálẹ̀ Sahara láti Bẹlu , 2024
Àwọn Obìnrin tó ń wa kùsà ní Áfíríkà: Àgbàsílẹ̀ Ìròyìn alálàyé tí Aïssatou Fofana ṣe
Isẹ́ ọkùnrin nìkan ni ọ̀pọ̀ eèyàn ka Wíwa kùsà sí . Àmọ́, àwọn obìnrin ti pọ̀ nídi iṣẹ́ tí ó ń gboòrò yìí.
Ipa tí ètò ẹja pípa orílẹ̀-èdè China ń kó lórí Ìwọ̀ Oòrùn Ilẹ̀ Áfríkà
Ìṣòro àyípadà ojú-ọjọ́ àti ẹja pípa lápajù ti mú ìdínkù bá ètò ẹja pípa orílẹ̀-èdè China, ó sì ti lé àwọn ọkọ̀ ìpẹja ńláńlá orílẹ̀-èdè China síta láti lọ máa pẹja lẹ́yìn odi. Àwọn apẹja Ìwọ Oòrùn Áfíríkà ló ń forí kó o.