Ìròyìn nípa Ìlú Gúúsù Aṣálẹ̀ Sahara láti Ọ̀wẹwẹ̀ , 2024
Àwọn Obìnrin ti ní àǹfààní sí ogún jíjẹ lábẹ́ òfin o, síbẹ̀ ẹnu àwọn obìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà kò tólẹ̀ lóri níní ìpín nínú ilẹ̀ pínpín.
"Àwọn ìjọba ò ní ẹ̀tọ́ látí fi ipá mú wa pé kí a máa fún àwọn ọmọbinrin wà ní ilẹ̀ nìtorí pe ọmọbìnrin á lọ sílé ọkọ..."