Ìròyìn nípa South Asia láti Ògún , 2019
Ìṣọdẹ-àjẹ́ ṣì ń gba ẹ̀mí àwọn ènìyàn ní ìgbèríko India
Ìṣọdẹ-àjẹ́ jẹ́ ìwà tí kò bójúmu tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní àwọn apá kan ní India níbi tí àwọn ènìyàn, tí a n pe ọ̀pọ̀ jẹ́ obìnrin, ni àjẹ́ tí a sábà máa ń fìyà jẹ láì dá wọn lẹ́jọ́