Ìròyìn nípa Ukraine
A lé òǹṣàmúlò TikTok Nekoglai láti Moscow padà sí Moldova pẹ̀lú àmì lúlù
“Orò ìjẹ̀bi àti ìtìjú” náà ni àwọn agbófinró orílẹ̀-èdè Russia pọwọ́lé lílò rẹ̀ láti fi “àbámọ̀” náà hàn ní gbangba àti ìpayà àwọn afẹ̀hónúhàn
Fún Ayẹyẹ Àìsùn Ọdún Tuntun àwọn Ilé-Ìwé ní Moscow, àwọn orin kan ò bójúmu
Ní àpapọ̀, àtòjọ náà ní àwọn olórin àti ẹgbẹ́ eléré 29. Díẹ̀ nínú wọn, bíi Little Big àti Manizha, ti ṣojú orílẹ̀-èdè Russia rí ní ìdíje Eurovision fún ọdún púpọ̀ látẹ̀yìnwá. Gbogbo wọn pata ni wọ́n bu ẹnu àtẹ́ lu ìkọlù orílẹ̀-èdè Russia sí Ukraine ní gbangba
Ohùn-kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́: Ìlọ́wọ́sí àwọn ìlú apá Ìwọ̀-Oòrùn nínú ìkógunjàlú tí Russia gbé ko Ukraine
"Láì sí àní-àní ògbò ogúnléndé Russia kò jẹ́bi tó ògbò olóṣèlú Germany" - Àwọn aṣáájú èrò Russia.