Ìròyìn nípa Trinidad & Tobago láti Ọ̀wẹwẹ̀ , 2019
Iyùn Tobago tí ó ti ń pàwọ̀dà fi hàn gbàgàdàgbagada pé kò sí ọ̀nà mìíràn ju kíkojú àyípadà ojú-ọjọ́
Ìgbóná òkun ń kóbá àwọn òkúta iyùn-un Tobago àti àwọn erékùṣù Ọ̀sàa Caribbean, a bá onímọ̀ ìṣẹ̀dá kan tí ọjọ́ iwájúu wọn jẹ́ lógún sọ̀rọ̀.