Ìròyìn nípa Iṣẹ́ ìkọ̀ròyìn àti Ìròyìn-kíkọ láti Ṣẹẹrẹ, 2020
Ẹ̀rọ Alátagbà ni a fi gbé àwọn ìròyìn irọ́ àti ọ̀rọ̀ ẹlẹ́yàmẹyà jáde lásìkò ìdìbò orílẹ̀-èdèe Nàìjíríà
Ìbò ọdún-un 2019 orílẹ̀-èdèe Nàìjíríà rí àwọn ọ̀rọ̀ ìkórìíra ẹ̀yà tẹ̀gbintẹ̀gbin láìròtẹ́lẹ̀ nípasẹ̀ẹ ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ àti ọ̀nà ìtànkálẹ̀ ìròyìn lórí ayélujára, pabambarì lóríi gbàgede Twitter.