Ìròyìn nípa Iṣẹ́ ìkọ̀ròyìn àti Ìròyìn-kíkọ láti Èrèlé , 2019
Olórí orílẹ̀-èdè Azerbaijan tàkùrọ̀sọ àkọ́kọ́ ní orí amóhùnmáwòrán lẹ́yìn ọdún 15 ní orí àlééfà. Ó lè lo ọ̀nà mìíràn.
"Ọ̀rọ̀ ìparíì mi: ara ò rọ ìjọba rárá!"
Ilé-iṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Ìbílẹ̀ Fagilé Ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú àwọn ajìjàǹgbara LGBT lẹ́yìn ìhalẹ̀mọ́ sí olóòtú

Èébú ìkórìíra-ìbálòpọ̀-láàárín-akọ-àti-akọ ní orí ayélujára kò ṣí ọkàn-an olóòtú kúrò, àmọ́ ìpè ẹni àjèjì ń dá ẹ̀ru ìwà ìkà bá àwọn àlejòo rẹ̀.