Ìròyìn nípa Ètò ìjọba láti Ọ̀wàrà , 2019
Ìrọ́lù ọlọ́pàá tí í mú ikú bá ‘ni ní Guinea bí Ààrẹ Alpha Condé ṣe kọ̀ láì gbé’ jọba sílẹ̀
Ìwà ipá ọlọ́pàá tí ó ń ṣekú pani ní Guinea bí ààrẹ ṣe gbèrò láti yí ìwé-òfin padà kí ó bá wà lórí ipò. Àwọn afẹ̀hónúhàn pa ẹni mẹ́fà àti ọlọ́pàá kan, ọ̀pọ́ sì fara pa.