· Ẹrẹ́nà , 2020

Ìròyìn nípa Ìdàgbàsókè láti Ẹrẹ́nà , 2020

Sísọnù sínú ògbufọ̀: Ìdí tí Atúmọ̀ Google ṣe ń kùnà — nínú títúmọ̀ èdè Yorùbá — àti àwọn èdè mìíràn

Ohùn Tó-ń-dìde  11 Ẹrẹ́nà 2020

Bí àwọn iléeṣẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ ṣe ń gbìyànjú láti mú kí ògbufọ̀ èdè wà lárọ̀ọ́wọ́tó fún onírúurú èdè lórí ayélujára, ni àríyànjiyàn àti ìpèníjà ń gbérí — pàápàá jù lọ ti àṣe déédéé àti ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ ọlọ́pọ̀ ìtumọ̀.