Ìròyìn nípa Ìròyìn Yàjóyàjó láti Igbe , 2020
Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà fi òfin de ìrìn-àjò lójúnà ìṣàmójútó àwọn tó ti kó kòkòrò àìfojúrí COVID 19
Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lórí ayélujára béèrè fún ìfòfindè arìnrìnàjò láti orílẹ̀-èdè tí COVID-19 ti gbilẹ̀. Èyí á ró ojúṣẹ́ orílẹ̀-èdè sí ìtànkálẹ̀ yìí lágbára.