Ìròyìn nípa Àṣà àti Iṣẹ́-ọnà láti Ẹrẹ́nà , 2020
Ọ̀rọ̀ àyálò nínú èdè Yorùbá: Bí èdè ṣe yí padà
Lílo àwọn ojúlówó ọ̀rọ̀ èdè Yorùbá pọ́nbélé máa ń mú kí àṣà — ó gbòòrò — tí yóò sí máa gbilẹ̀.
Olóyè yìí nírètí wí pé àwọn ọmọ Yorùbá yóò tẹ́wọ́ gba ‘alífábẹ́ẹ̀tì t'ó ń sọ̀rọ̀’ tí òun hu ìmọ̀ rẹ̀
Kíkọ Yorùbá nílànà Látíìnì yóò di àfìẹ́yìn láì pẹ́ nítorí ọmọ káàárọ̀-o-ò-jí-ire kan, Olóyè Tolúlàṣẹ Ògúntósìn, ti hùmọ̀ ìlànà ìṣọwọ́kọ tuntun fún kíkọ èdè Yorùbá