Alákòóso Global Voices RuNet Echo yóò ṣe ògbufọ̀ yóò sì kọ ìròyìn lórí ayélujára lédè Russian fún akàròyìn kárí ayé.

RSS

Ìròyìn láti Ìkùrìrì RuNet láti Igbe , 2019

Wọ́n fagi lé ìfìwépè Adarí iléeṣẹ́ tó ń ṣètò Ìṣàjò-papọ̀-wa-ọkọ̀-kí-n-wa-ọkọ̀ sí iléeṣẹ́ tẹlifíṣàn Russia lẹ́yìn tí olóòtú ètò rí i pé obìnrin ni

Russia ṣì ní iṣẹ́ tó pọ̀ láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìbádọ́gba akọ àti abo.