Àwọn àtẹ̀jáde yìí wá láti Ohùn Tó-ń-dìde, iṣẹ́ Global Voices tí ó ń ṣe àgbékalẹ̀ àti ìdàgbàsókè ìròyìn ọmọ ìlú ní àwọn ibi tí àwọn ènìyàn kò fi bẹ́ẹ̀ ń rí i.
Àìṣàfikún àwọn èdè abínibí ilẹ̀ Adúláwọ̀ nínú ìṣẹ̀dá àwọn ohun-èlò orí ẹ̀rọ-ayélujára yóò túbọ̀ mú kí àìdógba ìṣàmúlò ẹ̀rọ-ayélujára tí ó wà láàárín ilẹ̀ Adúláwọ̀ àti àwọn agbègbè mìíràn lágbàáyé ó peléke sí i.
Akitiyan àwọn aládàásí afinúfẹ́dọ̀, àwọn àjọ, àwọn ọlọ́rẹ àti àwọn tí iṣẹ́ wọ́n f'ara pẹ́ ti Global Voices ni ó ń ṣe àtìlẹ́yìn. Fún ìwífún sí i jọ̀wọ́ ka Òfin Ìwà Ìkówójọ wa: Fundraising Ethics
Ọ̀pẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ alátìlẹ́yìn àti àwọn agbátẹrù wa : sponsors and funders