Ìròyìn nípa Ohùn Tó-ń-dìde
Túwíìtì nípa èdè Ilẹ̀-Adúláwọ̀ àti ẹ̀tọ́ sí ìlò ẹ̀rọ ayárabíàṣá
Rising Voices ń kọ́mọlùbọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ẹ wa ní yàrá ìròyìn Ohùn Àgbáyé Agbègbè Sahara Ilẹ̀-Adúláwọ̀ fún ìpolongo tuntun lórí ẹ̀rọ alátagbà láti ṣe àyẹ̀wò ìbáṣepọ̀ tí ó ń bẹ láàárín àwọn èdè Ilẹ̀-Adúláwọ̀ àti ẹ̀tọ́ sí ẹ̀rọ ayárabíàṣá.
Twitter @DigiAfricanLang 2019
Tweets by @DigiAfricanLang Bẹ̀rẹ̀ láti ogúnjọ́ oṣù Ẹrẹ́nà títí di òpin ọdún-un 2019, àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ ní orí ẹ̀rọ ayárabíàṣá á máa ṣe ‘ọ̀ọ̀wẹ̀’ láti ṣàkóso aṣàmúlò Túwítà @DigiAfricanLang ní...
Bí àpamọ́ àlọ́ àti ìtàn àtọwọ́dọ́wọ́ ṣe mú ọ̀rọ̀ àyíká di mímọ̀ ní Mekong
"By means of stories, the communities search for ways to accommodate and/or resist changes that are taking place in the Mekong river basin."