Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Sikiru Jamiu Ọláwálé láti Ṣẹẹrẹ, 2023
Ó rọrùn, lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, ó sì bani nínú jẹ́ — òṣùwọ̀n àwọn àjọ̀dún
" ... Ohun tí mo ní pẹ̀lú Ọjọ́ Àìsùn Ọdún tuntun wá láti èrò ìgbà èwe, èrò tó fi yé mi pé àwọn idán àràmàndà lè ṣẹlẹ̀."