Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Sikiru Jamiu Ọláwálé
Ó rọrùn, lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, ó sì bani nínú jẹ́ — òṣùwọ̀n àwọn àjọ̀dún
" ... Ohun tí mo ní pẹ̀lú Ọjọ́ Àìsùn Ọdún tuntun wá láti èrò ìgbà èwe, èrò tó fi yé mi pé àwọn idán àràmàndà lè ṣẹlẹ̀."
O rí gbogbo èdè òkè wọ̀nyẹn? A ṣe ìtumọ̀ ìròyìn Global Voices (Ohun Àgbáyé) láti mú ìròyìn ará ìlú àgbáyé sétígbọ̀ọ́ ènìyàn gbogbo.
" ... Ohun tí mo ní pẹ̀lú Ọjọ́ Àìsùn Ọdún tuntun wá láti èrò ìgbà èwe, èrò tó fi yé mi pé àwọn idán àràmàndà lè ṣẹlẹ̀."