Ọmọ Yoòbá

Ímeèlì Ọmọ Yoòbá

Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Ọmọ Yoòbá

Àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Brazili ra ìpín ìdókòòwò ní iléeṣẹ́ reluwé láti bá a wí fún ìkùnà ojúṣe àyíkáa rẹ̀

Ìlépa alájọpín-ìdókòòwòo wọn kì í ṣe fún ti èrè ìdókòòwò, àmọ́ láti mú kí ohùn-un wọn ó dé etí ìgbọ́ àwọn olùdókòòwòo iléeṣẹ́ náà.

Ìjọba Tanzania fi Ajìjàgbara Ọmọ Orílẹ̀-èdèe Uganda sí àtìmọ́lé, wọ́n sì lé e kúrò nílùú

Human Rights Watch sọ wípé Orílẹ̀ èdèe Tanzania ti rí "ìrésílẹ̀ ìbọ̀wọ̀ fún òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ, ìkẹ́gbẹ́ àti àpéjọ dé ojú àmì" lábẹ́ ìṣàkóso ìjọba...

Oníròyìn Orí ẹ̀rọ-alátagbà Luis Carlos Diaz di àwátì ní Venezuela

Luis Carlos "jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó síwájú nínú akọ̀ròyìn tako ìgbésẹ̀ ìjọba ní Venezuela".

Àfilé iye owó fún gbígba ìwé ẹ̀rí ọmọ-ìlú-fún-ìrìnnà mú àwọn ọmọ Angola fi ẹ̀hónú hàn

Iye owó ìwé ẹ̀rí náà fò sókè láti owó dollar orílẹ̀-èdè US 8 sí 97.

Akẹ́kọ̀ọ́bìrin kan tí ó jẹ́ ọmọ Tibet-Canada rí ìkọlu lórí ayélujára lẹ́yìn tí ó já ewé olú borí nínú ìdìbò àjọ-ìgbìmọ̀ akẹ́kọ̀ọ́. Ó rò pé, Beijing ló yẹ á bá wí.

Chemi Lhamo dojú kọ onírúurú èsì ìdáyàjáni ní orí ẹ̀rọ-alátagbà láti ẹnu àwọn akẹ́kọ̀ọ́ òkè-òkun tí ó ń gbé ní gbùngbùn orílẹ̀-èdè China.

Olórí orílẹ̀-èdè Azerbaijan tàkùrọ̀sọ àkọ́kọ́ ní orí amóhùnmáwòrán lẹ́yìn ọdún 15 ní orí àlééfà. Ó lè lo ọ̀nà mìíràn.

"Ọ̀rọ̀ ìparíì mi: ara ò rọ ìjọba rárá!"

Jẹ́ kí àwọn òkú ó sọ ìtàn nípa Hong Kong

"Ìrìnàjò afẹ́ ìpànìyàn" tí ó ń lépa láti ṣe àyẹ̀wò fínnífínní sí" ìtúmọ̀ ayé àti ìgbé-àyè" ní àyìkà agbègbè orílẹ̀-èdèe Hong Kong.

‪Ta ni yóò jáwé olúborí nínú Ayẹyẹ ijó ìta-gbangba orílẹ̀-èdè Trinidad àti Tobago ọdún-un 2019?‬

Orin tí ó dùn ún gbọ́ létí, ègbè tí ó ṣòro láti gbàgbé ... jẹ́ díẹ̀ lára àwọn ohun idán tí ó mú orin Ijó...

Pẹ̀lú àìbalẹ̀-ọkàn tí ó ń pọ̀ sí i ní ìmúra ìbò ààrẹ ọdún-un 2019, Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń bẹ̀rùu pípa ẹ̀rọ-ayélujára

Lílo ẹ̀rọ-alátagbà fún pípe àkíyèsí sí ìrúfin ìjọba àti ìwà tí kò bá òfin mu ti fa ìbẹ̀rù wípé ìtẹríbọlẹ̀ ní orí ayélujára ní àsìkò...

Òwìwí kan kọ̀ kò kúrò nínú ilé ìgbìmọ̀ ìjọba Tanzania. Àmìi kí ni èyí?

The owl appeared while signing a controversial amendment limiting opposition voices in Tanzania. Could the owl be an omen signaling the death of democracy in...