Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Ọlásúnkànmí Ọlámìídé láti Ọ̀pẹ, 2022
Àwọn àjòjì tí wọ́n gba òmìnira sọ ìrírí wọn ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Myanmar
"Mà á fẹ́ láti ṣàtẹnumọ́ pé àwọn tí kò nífọ̀n-léèékánná lọ̀pọ̀ àwọn olùfaragbá ìyà àwọn ológun, èyí tí ó sì ń tẹ̀síwajú."