Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Ọlásúnkànmí Ọlámìídé
Àwọn àjòjì tí wọ́n gba òmìnira sọ ìrírí wọn ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Myanmar
"Mà á fẹ́ láti ṣàtẹnumọ́ pé àwọn tí kò nífọ̀n-léèékánná lọ̀pọ̀ àwọn olùfaragbá ìyà àwọn ológun, èyí tí ó sì ń tẹ̀síwajú."
O rí gbogbo èdè òkè wọ̀nyẹn? A ṣe ìtumọ̀ ìròyìn Global Voices (Ohun Àgbáyé) láti mú ìròyìn ará ìlú àgbáyé sétígbọ̀ọ́ ènìyàn gbogbo.
"Mà á fẹ́ láti ṣàtẹnumọ́ pé àwọn tí kò nífọ̀n-léèékánná lọ̀pọ̀ àwọn olùfaragbá ìyà àwọn ológun, èyí tí ó sì ń tẹ̀síwajú."